African Music Elijah Daniel – Ijinle Ninu Ijinle

Elijah Daniel – Ijinle Ninu Ijinle

Ijinle Ninu Ijinle by Elijah Daniel

NEW 2024 LATEST GOSPEL MUSIC ALERT; ijinle ninu ijinle MP3 by Check-Out this amazing brand new single + the Lyrics of the song and the official music-video titled ijinle ninu ijinle by a renowned & anointed Christian music artist Elijah Daniel

Stream and Download this amazing mp3 audio single for free and don't forget to share with your friends and family for them to be a blessed through this powerful & melodius gospel music, and also don't forget to drop your comment using the comment box below, we look forward to hearing from you. Thanks!! . #GospelJingle

DOWNLOAD HERE

Elijah Daniel ijinle ninu ijinle Lyrics
Ana mi soro …. Eseun o
Oni mi soro ……Eseun o
Ola mi a soro ….Eseun o
Ijinle ninu ijinle Eseun oo ×4

Ana mi soro …. Eseun o
Oni mi soro ……Eseun o
Ola mi a soro ….Eseun o
Ijinle Ninu ijinle Eseun oo ×5

Ana mi soro …. Eseun o
Oni mi soro ……Eseun o
Ola mi a soro ….Eseun o
Ijinle Ninu ijinle Eseun oo ×2
Ese olore ofe ooo
Ijinle Ninu ijinle ese ooo ×3

Tori wipe
Ana mi soro …. Eseun o
Oni mi soro ……Eseun o
Ola mi a soro ….Eseun o
Ijinle Ninu ijinle Eseun oo ×2
Ijinle that's who you are
Ijinle Ninu ijinle Eseun oo
Oran Omo nise fayati …..Eseun o
Aran ni Ba ni lo ooo ……Eseun o

Oba ti kin dojutini ……Eseun o
Ijinle Ninu ijinle ……Eseun o
Eru toun gberu mi
Ijinle Ninu ijinle …. Eseun o
Oro toun so gbogbo Oro…..Eseun o
Olorun ti ko see daduro ….. Eseun o
Olorun to'mo iye irun Ori mi o….Eseun oo
Ijinle Ninu ijinle …….Eseun o
Aditu nla lo'ro re o……Eledumare ode
Ijinle Ninu ijinle….. Eseun o

Ana mi soro …. Eseun o
Oni mi soro ……Eseun o
Ola mi a soro ….Eseun o
Ijinle Ninu ijinle …..Eseun o
My God
You're the ijinle Ninu ijinle
Ana mi soro……Oseun o
Oni mi soro……Oseun o
Ola mi a soro ….Oseun o
Ijinle Ninu ijinle…..Oseun o

Ana mi soro …. Eseun o
Oni mi soro ……Eseun o
Ola mi a soro ….Eseun o

Jesu mi ooooo ×2
Jesu mi Jesu mi
Ijinle Ninu ijinle……Ose o
Oro Ninu Oro, agbara Ninu agbara
Jesu mi …..iyin loye o
Aditu nla lo'ro re …..kosetu wo
Ijinle Ninu ijinle……Ose ooo
Ojo to pa alaboyun…..ti ko pa Omo inu e
Ijinle Ninu ijinle….Oseun ooo
B'egungun se n'dagba Ninu alaboyun
Iwo loye, Iwo lo mo oo
Ijinle Ninu ijinle modupe o
Ijinle Ninu ijinle Oseun oo

Oda omi, Oda Eja
You created the heaven
You created the Earth
Ijinle Ninu ijinle
Oro Ninu Oro
Mogbe o ga
Agbara Ninu agbara o …..iyin ye o
Ijinle Ninu ijinle …..Oseun o

Ijinle Ninu ijinle ….. Oseun ooo ×3

Olore ofe
Eleru niyin
Olorun agbaye
Mogbe oga

Olore ofe
Eleru niyin
Olorun agbaye
Mogbe oga

Olore ofe
Eleru niyin
Olorun agbaye
Mogbe oga

Olore ofe
Eleru niyin
Olorun agbaye
Mogbe oga

Tori pe
Ana mi soro …. Eseun o
Oni mi soro ……Eseun o
Ola mi a soro ….Eseun o
Ijinle Ninu ijinle…… Oseun o ×2

Oya baba agba arugbo ojo o
Iwo loye lati gba ogo Iwo loye
Baba agba arugbo ojo o
Iwo loye lati gba ogo Iwo loye

Emi kole se, ke'mi ma yin oluwa o
Emi kole se ke'mi ma yin oluwa o
Baba mi loje olorun agbalagba
Baba mi loje olorun agba oye
Emi kole se ke'mi ma yin oluwa o hallelujah
Ijinle Ninu ijinle Oseun o ×4

Tori wipe
Ana mi soro …. Eseun o
Oni mi soro ……Eseun o
Ola mi a soro ….Eseun o
Ijinle Ninu ijinle Oseun o

Because I am a winner
Winner winner
Moti di winner jhor
Over poverty
I am a Winner over sorrow
I am a winner over debt
No weapon fashioned against me shall prosper

I am a winner
Over poverty
I am a Winner over sorrow
I am a winner over debt
No weapon fashioned against me shall prosper

I am a winner
Over poverty
I am a Winner over sorrow
I am a winner over debt
No weapon fashioned against me shall prosper

Ana mi soro …. Eseun o
Oni mi soro ……Eseun o
Ola mi a soro ….Eseun o
Ijinle Ninu ijinle Oseun o ×5

Ana mi soro …. Eseun o
Oni mi soro ……Eseun o Odamiloju pe
Ola mi a soro ….Eseun o
Ijinle Ninu ijinle …Oseun oo

Ana mi soro …. Eseun o
Oni mi soro ……Eseun o
Ola mi a soro ….Eseun o
Ijinle Ninu ijinle …Oseun oo

Ijinle Ninu ijinle Oseun o ×2
Oranmo nise fayati ….. Oseun o
Adagba ma te'pa …… Arugbo ojo o
Giga giga Ninu olanla ooo…… Eledumare ooo
Atofise Ogun ran , ajanaku tin migbo kiji kiji
Ajade mama tan nile oloruko iyanu
Okurin Ogun
Mimo mimo mimo …..kabi esi ooo
Ijinle Ninu ijinle Oseun o ×2
Thank God Jesus

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here