African Music Nifemi David – Eyinju (Mp3 + Lyrics)

Nifemi David – Eyinju (Mp3 + Lyrics)

Auto Draft

Audio Music Download Nifemi David – Eyinju MP3 by Nifemi David

Check-Out this amazing brand new single + the Lyrics of the song and the official music-video titled Eyinju by a Renowned and anointed Christian / Gospel singer and recording music artist whose mission is to be a blessing many people through kingdom music.

  • Song Title: Mp3 Eyinju FREE DOWNLOAD Eyinju by Nifemi David
  • Genre: Gospel
  • Released: 2023
  • Duration: 04:17

Stream and Download this amazing mp3 audio single for free and don't forget to share with your friends and family for them to be a blessed through this powerful & melodius gospel music, and also don't forget to drop your comment using the comment box below, we look forward to hearing from you. Thanks!! . #GospelJingle

DOWNLOAD HERE

Nifemi David Eyinju Lyrics
K'ato to d'omo lo ti mo mi
O pe mi leyin ju
Ki n to d'omo loti mo'hun maa da o
Ogo fun eni to da mi
K'ato to d'omo lo ti mo mi
O pe mi leyin ju
Ki n to d'omo loti mo'hun maa da o
Ogo fun eni to da mi

Ewe kan ko ni jabo
Koseyin Olodumare
Ohun ti mo maa da ti mo hun da lowo
Oti wa ninu eto baba aa o
Eledaa to da mi
O mase ee oo

Ke'je to d'omo lo ti mo mi
O pe mi leyin ju
Ki n to d'omo loti mo'hun maa da o
Ogo fun eni to da mi

Eto olorun nimi
Eda aye ole Pemi lasise
Ninu eto olorun ni Mo wa
Eyi Lofi feto fun mi
Eto eyi logo
Tosemi yato
A o kan dami kan lasan
O laa dami ni iri ohun
And He took it personal
O pe mi ni ogo o
Ola ire
Ọrọ ibukun replete
Eyin sha leri ife oluwa simi iii pe

K'ato to d'omo lo ti mo mi
O pe mi leyin ju
Ki n to d'omo loti mo'hun maa da o
Ogo fun eni to da mi

Keda aye masere ohun towa Leto
Mi o ni o duro sugbon makanju
Ma de sare asaju laye
Eleto ni'seda ko ni re o je
O waa ninu eto
Eto ate o lowo Boya o
Oti momi o
Kato dami sinu
Ki n to tinu jade
Loti somi di Mimo
Ayami Soto
Aye mi n bu ola fun ida ti o lasise e
Peki ni re se lodo emi
Eyinju baba

O n f'ogo fun hmmmm
(Aye emi naa to da)
O n f'ola fun
(O n fogo fun eda ara oto)
O n f'ogo fun hmmmm
(Ida to da mi Ola sise)
O n f'ola fun
(Modupe feleto to kami meto)
O n f'ogo fun hmmmm
(Ose e aye mi n fogo fun)
O n f'ola fun

K'eje to d'omo lo ti mo mi
O pe mi leyin ju
Ki n to d'omo loti mo'hun maa da o
Ogo fun eni to da mi

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here